Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 14:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ha ti kọ̀ Juda silẹ patapata? ọkàn rẹ ti korira Sioni? ẽṣe ti iwọ ti lù wa, ti imularada kò si fun wa? awa nreti alafia, kò si si rere, ati fun igba imularada, ṣugbọn wò o, idãmu!

Ka pipe ipin Jer 14

Wo Jer 14:19 ni o tọ