Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 14:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi emi ba jade lọ si papa, sa wò o, a ri awọn ti a fi idà pa! bi emi ba si wọ inu ilu lọ, sa wò o, awọn ti npa ọ̀kakà ikú nitori iyan! nitori awọn, ati awọn woli, ati awọn alufa nwọ́ lọ si ilẹ ti nwọn kò mọ̀.

Ka pipe ipin Jer 14

Wo Jer 14:18 ni o tọ