Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Fadaka ti a fi ṣe awo ni a mu lati Tarṣiṣi wá, ati wura lati Upasi wá, iṣẹ oniṣọna, ati lọwọ alagbẹdẹ: alaro ati elese aluko ni aṣọ wọn: iṣẹ ọlọgbọ́n ni gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Jer 10

Wo Jer 10:9 ni o tọ