Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 10:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Oluwa, Ọlọrun otitọ ni, on ni Ọlọrun alãye, ati Ọba aiyeraiye! aiye yio warìri nigbati o ba binu, orilẹ-ède kì yio le duro ni ibinu rẹ̀.

Ka pipe ipin Jer 10

Wo Jer 10:10 ni o tọ