Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jer 10:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tu ibinu rẹ si ori awọn orilẹ-ède, ti kò mọ̀ ọ, ati sori awọn idile ti kò ke pè orukọ rẹ, nitoriti nwọn ti jẹ Jakobu run, nwọn si gbe e mì, nwọn si pa a run tan, nwọn si sọ ibugbe rẹ̀ di ahoro.

Ka pipe ipin Jer 10

Wo Jer 10:25 ni o tọ