Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 65:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki yio si ọmọ-ọwọ nibẹ ti ọjọ rẹ̀ kì yio pẹ́, tabi àgba kan ti ọjọ rẹ̀ kò kún: nitori ọmọde yio kú li ọgọrun ọdun; ṣugbọn ẹlẹṣẹ ọlọgọrun ọdun yio di ẹni-ifibu.

Ka pipe ipin Isa 65

Wo Isa 65:20 ni o tọ