Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 58:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì ha ṣe lati fi onjẹ rẹ fun awọn ti ebi npa, ati ki iwọ ki o mu awọn otòṣi ti a tì sode wá si ile rẹ? nigbati iwọ ba ri arinhòho, ki iwọ ki o bò o, ki iwọ, ki o má si fi ara rẹ pamọ kuro lọdọ ẹran-ara tirẹ.

Ka pipe ipin Isa 58

Wo Isa 58:7 ni o tọ