Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 55:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ tẹtilelẹ, ki ẹ si wá sọdọ mi: ẹ gbọ́, ọkàn nyin yio si yè: emi o si ba nyin dá majẹmu ainipẹkun, ãnu Dafidi ti o daju.

Ka pipe ipin Isa 55

Wo Isa 55:3 ni o tọ