Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 52:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

JI! ji! gbe agbara rẹ wọ̀, iwọ Sioni; gbe aṣọ ogo rẹ wọ̀, iwọ Jerusalemu, ilu mimọ́: nitori lati igbayi lọ, alaikọla on alaimọ́ kì yio wọ̀ inu rẹ mọ.

Ka pipe ipin Isa 52

Wo Isa 52:1 ni o tọ