Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 5:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni ibinu Oluwa fi ràn si enia rẹ̀, o si ti na ọwọ́ rẹ̀ si wọn, o si ti lù wọn: awọn òke si warìri, okú wọn si wà bi igbẹ li ãrin igboro. Ni gbogbo eyi ibinu rẹ̀ kò yi kuro, ṣugbọn ọwọ́ rẹ̀ nà jade sibẹ.

Ka pipe ipin Isa 5

Wo Isa 5:25 ni o tọ