Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 5:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bi iná ti ijo akekù koriko run, ti ọwọ́ iná si ijo iyàngbo; bẹ̃ni egbò wọn yio da bi rirà; itanna wọn yio si gòke bi ekuru; nitori nwọn ti ṣá ofin Oluwa awọn ọmọ-ogun tì, nwọn si ti gàn ọ̀rọ Ẹni-Mimọ Israeli.

Ka pipe ipin Isa 5

Wo Isa 5:24 ni o tọ