Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 48:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li atetekọṣe ni mo tilẹ ti sọ fun ọ; ki o to de ni emi ti fihàn ọ: ki iwọ má ba wipe, Oriṣa mi li o ṣe wọn, ati ere mi gbigbẹ́, ati ere mi didà li o ti pa wọn li aṣẹ.

Ka pipe ipin Isa 48

Wo Isa 48:5 ni o tọ