Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 47:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni ibi yio ṣe ba ọ; iwọ ki yio mọ̀ ibẹrẹ rẹ̀: ibi yio si ṣubu lù ọ; ti iwọ kì yio le mu kuro: idahoro yio deba ọ lojiji, iwọ kì yio si mọ̀.

Ka pipe ipin Isa 47

Wo Isa 47:11 ni o tọ