Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 47:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ti iwọ ti gbẹkẹle ìwa buburu rẹ: iwọ ti wipe, Kò si ẹnikan ti o ri mi. Ọgbọ́n rẹ ati ìmọ rẹ, o ti mu ọ ṣinà; iwọ si ti wi li ọkàn rẹ pe, Emi ni, ko si ẹlomiran lẹhin mi.

Ka pipe ipin Isa 47

Wo Isa 47:10 ni o tọ