Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 45:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lõtọ, a o wipe, ninu Oluwa li emi ni ododo ati agbara: sọdọ rẹ̀ ni gbogbo enia yio wá; oju o si tì gbogbo awọn ti o binu si i.

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:24 ni o tọ