Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 45:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ sọ ọ, ki ẹ si mu wá, lõtọ, ki nwọn ki o jọ gbimọ̀ pọ̀: tali o mu ni gbọ́ eyi lati igbãni wa? tali o ti sọ ọ lati igba na wá? emi Oluwa kọ? ko si Ọlọrun miran pẹlu mi; Ọlọrun ododo ati Olugbala; ko si ẹlomiran lẹhin mi.

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:21 ni o tọ