Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 45:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo ti gbe e dide ninu ododo, emi o si mu gbogbo ọ̀na rẹ̀ tọ́; on o kọ́ ilu mi, yio si dá awọn ondè mi silẹ: ki iṣe fun iye owo tabi ère, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.

Ka pipe ipin Isa 45

Wo Isa 45:13 ni o tọ