Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 44:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni Oluwa wi, Ọba Israeli, ati Olurapada rẹ, Oluwa awọn ọmọ-ogun; Emi ni ẹni-ikini, ati ẹni-ikẹhin; ati lẹhin mi ko si Ọlọrun kan.

Ka pipe ipin Isa 44

Wo Isa 44:6 ni o tọ