Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 43:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ko fi owo rà kalamu olõrun didun fun mi, bẹ̃ni iwọ ko fi ọra ẹbọ rẹ yó mi; ṣugbọn iwọ fi ẹ̀ṣẹ rẹ mu mi ṣe lãla, iwọ si fi aiṣedẽde rẹ da mi li agara.

Ka pipe ipin Isa 43

Wo Isa 43:24 ni o tọ