Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 43:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ko mu ọmọ-ẹran ẹbọ sisun rẹ fun mi wá; bẹ̃ni iwọ ko fi ẹbọ rẹ bu ọlá fun mi. Emi ko fi ọrẹ mu ọ sìn, emi ko si fi turari da ọ li agara.

Ka pipe ipin Isa 43

Wo Isa 43:23 ni o tọ