Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 42:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si mu awọn afọju bá ọ̀na ti nwọn kò mọ̀ wá; emi o tọ́ wọn ninu ipa ti wọn kò ti mọ̀; emi o sọ okùnkun di imọlẹ niwaju wọn, ati ohun wiwọ́ di titọ. Nkan wọnyi li emi o ṣe fun wọn, emi kì yio si kọ̀ wọn silẹ.

Ka pipe ipin Isa 42

Wo Isa 42:16 ni o tọ