Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 37:38 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si di igbati o ṣe, bi o ti ntẹriba ni ile Nisroki oriṣa rẹ̀, ni Adrammeleki ati Ṣaresari awọn ọmọ rẹ̀ fi idà pa a; nwọn si salà si ilẹ Armenia: Esarhaddoni ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin Isa 37

Wo Isa 37:38 ni o tọ