Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o li orin kan, gẹgẹ bi igbati a nṣe ajọ li oru; ati didùn inu, bi igbati ẹnikan fun fère lọ, lati wá si òke-nla Oluwa, sọdọ Apata Israeli.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:29 ni o tọ