Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Imọ́lẹ oṣupa yio si dabi imọ́lẹ õrun, imọ́lẹ õrun yio si ràn ni iwọ̀n igbà meje, bi imọ́lẹ ọjọ meje, li ọjọ ti Oluwa dí yiya awọn enia rẹ̀, ti o si ṣe àwotán ọgbẹ ti a ṣá wọn.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:26 ni o tọ