Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lori gbogbo oke-nla giga, ati lori gbogbo oke kékèké ti o ga, ni odò ati ipa-omi yio wà li ọjọ pipa nla, nigbati ile-iṣọ́ wọnni bá wó.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:25 ni o tọ