Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn enia Sioni yio gbe Jerusalemu, iwọ kì yio sọkun mọ: yio ṣanu fun ọ gidigidi nigbati iwọ ba nkigbe; nigbati on ba gbọ́ ọ, yio dá ọ lohùn.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:19 ni o tọ