Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 30:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni Oluwa yio duro, ki o le ṣe ore fun nyin, ati nitori eyi li o ṣe ga, ki o le ṣe iyọ́nu si nyin: nitori Oluwa li Ọlọrun idajọ: ibukun ni fun gbogbo awọn ti o duro dè e.

Ka pipe ipin Isa 30

Wo Isa 30:18 ni o tọ