Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 27:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ẹka inu rẹ̀ ba rọ, a o ya wọn kuro: awọn obinrin de, nwọn si tẹ̀ iná bọ̀ wọn: nitori alaini oye enia ni nwọn: nitorina ẹniti o dá wọn kì yio ṣãnu fun wọn, ẹniti o si mọ wọn kì yio fi ojurere hàn wọn.

Ka pipe ipin Isa 27

Wo Isa 27:11 ni o tọ