Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 25:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni oke-nla yi li Oluwa awọn ọmọ-ogun yio sè asè ohun abọ́pa fun gbogbo orilẹ-ède, asè ọti-waini lori gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ, ti ohun abọpa ti o kún fun ọra, ti ọti-waini ti o tòro lori gẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ.

Ka pipe ipin Isa 25

Wo Isa 25:6 ni o tọ