Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isa 24:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati opin ilẹ li awa ti gbọ́ orin, ani ogo fun olododo. Ṣugbọn emi wipe, Iparun mi, iparun mi, egbé ni fun mi! awọn ọ̀dalẹ ti dalẹ: nitõtọ, awọn ọ̀dalẹ dalẹ rekọja.

Ka pipe ipin Isa 24

Wo Isa 24:16 ni o tọ