Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o gbọ́ lati ọrun, ani lati ibugbe rẹ wá, ki o si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti alejo na kepe ọ si; ki gbogbo enia aiye ki o le mọ̀ orukọ rẹ, ki nwọn ki o si le ma bẹ̀ru rẹ̀, bi Israeli enia rẹ, ki nwọn ki o le mọ̀ pe orukọ rẹ li a npè mọ ile yi ti emi kọ́.

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:33 ni o tọ