Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu niti alejo, ti kì iṣe inu Israeli, enia rẹ, ṣugbọn ti o ti ilẹ òkere jade wá nitori orukọ nla rẹ, ati ọwọ agbara rẹ ati ninà apa rẹ; bi nwọn ba wá ti nwọn ba si gbadura siha ile yi:

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:32 ni o tọ