Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o gbọ́ lati ọrun, ibugbe rẹ wá, ki o si dariji, ki o si san a fun olukuluku gẹgẹ bi gbogbo ọ̀na rẹ̀, bi iwọ ti mọ̀ ọkàn rẹ̀; (nitori iwọ nikanṣoṣo li o mọ̀ ọkàn awọn ọmọ enia:)

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:30 ni o tọ