Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Adura ki adura, tabi ẹ̀bẹ ki ẹ̀bẹ ti a ba ti ọdọ ẹnikẹni gbà, tabi ọdọ gbogbo Israeli enia rẹ, nigbati olukuluku ba mọ̀ ipọnju rẹ̀, ati ibanujẹ rẹ̀, ti o ba si tẹ́ ọwọ rẹ̀ mejeji siha ile yi:

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:29 ni o tọ