Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, Oluwa, Ọlọrun Israeli, ba iranṣẹ rẹ Dafidi, baba mi pa eyi ti iwọ ti ṣe ileri fun u mọ́, wipe, A kì yio fẹ ọkunrin kan kù li oju mi lati joko lori itẹ́ Israeli: kiki bi awọn ọmọ rẹ ba kiyesi ọ̀na wọn, lati ma rìn ninu ofin mi, bi iwọ ti rìn niwaju mi.

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:16 ni o tọ