Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 6:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ti o ti ba iranṣẹ rẹ Dafidi baba mi, pa eyi ti iwọ ti ṣe ileri fun u mọ́; ti iwọ si ti fi ẹnu rẹ sọ, ti iwọ si ti fi ọwọ rẹ mu u ṣẹ, bi o ti ri loni yi.

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:15 ni o tọ