Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 36:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọdun kini Kirusi, ọba Persia, ki ọ̀rọ Oluwa lati ẹnu Jeremiah wá ki o le ṣẹ, Oluwa ru ẹmi Kirusi, ọba Persia, soke, ti o si ṣe ikede ni gbogbo ijọba rẹ̀, o si kọ iwe pẹlu, wipe,

Ka pipe ipin 2. Kro 36

Wo 2. Kro 36:22 ni o tọ