Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wó pẹpẹ Baalimu lulẹ niwaju rẹ̀; ati awọn ere õrun ti o wà lori wọn li o ké lulẹ; ati awọn ere-oriṣa, ati awọn ere yiyá, ati awọn ere didà, li o fọ tũtu, o sọ wọn di ekuru, o si gbọ̀n ọ sori isa-okú awọn ti o ti nrubọ́ si wọn.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:4 ni o tọ