Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori li ọdun kẹjọ ijọba rẹ̀, nigbati o si wà li ọdọmọde sibẹ, o bẹ̀rẹ si iwá Ọlọrun Dafidi, baba rẹ̀; ati li ọdun kejila, o bẹ̀rẹ si iwẹ̀ Juda ati Jerusalemu mọ́ kuro ninu ibi giga wọnni, ati ere-oriṣa, ati ere yiyá, ati ere didà.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:3 ni o tọ