Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 34:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si duro ni ipò rẹ̀, o si dá majẹmu niwaju Oluwa lati ma fi gbogbo aiya ati gbogbo ọkàn rìn tọ̀ Oluwa lẹhin, ati lati pa ofin rẹ̀ mọ́, ati ẹri rẹ̀, ati aṣẹ rẹ̀, lati ṣe ọ̀rọ majẹmu na ti a kọ sinu iwe yi.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:31 ni o tọ