Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 24:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kó awọn alufa ati awọn ọmọ Lefi jọ, o si wi fun wọn pe, Ẹ jade lọ si ilu Juda wọnni, ki ẹ si gbà owo jọ lati ọwọ gbogbo Israeli, lati tun ile Ọlọrun nyin ṣe li ọdọdun, ki ẹ si mu ọ̀ran na yá kankan. Ṣugbọn awọn ọmọ Lefi kò mu ọ̀ran na yá kánkan.

Ka pipe ipin 2. Kro 24

Wo 2. Kro 24:5 ni o tọ