Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 23:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Jehoiada alufa mu awọn olori ọrọrun ani awọn olori ogun na jade, o si wi fun wọn pe, Ẹ mu u jade kuro ninu ile sẹhin àgbala: ẹni-kẹni ti o ba si tọ̀ ọ lẹhin, ni ki a fi idà pa. Nitori alufa wipe, Ẹ máṣe pa a ninu ile Oluwa.

Ka pipe ipin 2. Kro 23

Wo 2. Kro 23:14 ni o tọ