Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 22:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wá Ahasiah: nwọn si mu u, (on sa ti fi ara pamọ́ ni Samaria,) nwọn si mu u tọ̀ Jehu wá: nigbati nwọn si pa a tan, nwọn sìn i: nitori ti nwọn wipe, ọmọ Jehoṣafati ni, ẹniti o wá Oluwa tọkàntọkan rẹ̀. Bẹ̃ni kò si ẹnikan ni ile Ahasiah ti o yẹ fun ijọba.

Ka pipe ipin 2. Kro 22

Wo 2. Kro 22:9 ni o tọ