Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 22:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe nigbati Jehu nmu idajọ ṣẹ sori ile Ahabu, o si ri awọn ijoye Juda, ati awọn ọmọ awọn arakunrin Ahasiah, ti nṣe iranṣẹ fun Ahasiah, o si pa wọn.

Ka pipe ipin 2. Kro 22

Wo 2. Kro 22:8 ni o tọ