Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 22:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹni ọdun mejilelogun ni Ahasiah, nigbati o bẹ̀rẹ si ijọba, o si jọba ọdun kan ni Jerusalemu. Orukọ iya rẹ̀ si ni Ataliah, ọmọbinrin Omri.

Ka pipe ipin 2. Kro 22

Wo 2. Kro 22:2 ni o tọ