Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 22:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

AWỌN olugbe Jerusalemu, si fi Ahasiah, ọmọ rẹ̀ abikẹhin, jọba ni ipò rẹ̀: nitori awọn ẹgbẹ́ ogun, ti o ba awọn ara Arabia wá ibudo, ti pa gbogbo awọn ẹgbọn. Bẹ̃ni Ahasiah, ọmọ Jehoramu, ọba Juda, jọba.

Ka pipe ipin 2. Kro 22

Wo 2. Kro 22:1 ni o tọ