Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ibi ba de si wa, bi idà, ijiya tabi àjakalẹ-àrun, tabi ìyan, bi awa ba duro niwaju ile yi, ati niwaju rẹ, (nitori orukọ rẹ wà ni ile yi): bi a ba ke pè ọ ninu wàhala wa, nigbana ni iwọ o gbọ́, iwọ o si ṣe iranlọwọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:9 ni o tọ