Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi, kiyesi i, awọn ọmọ Ammoni ati Moabu, ati awọn ara òke Seiri, ti iwọ kò jẹ ki Israeli gbogun si nigbati nwọn jade ti ilẹ Egipti wá, ṣugbọn nwọn yipada kuro lọdọ wọn, nwọn kò si run wọn;

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:10 ni o tọ