Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Elieseri ọmọ Dodafah ti Mareṣa sọtẹlẹ si Jehoṣafati wipe, Nitori ti iwọ ti dá ara rẹ pọ̀ mọ Ahasiah, Oluwa ti ba iṣẹ rẹ jẹ. Awọn ọkọ̀ na si fọ́, nwọn kò si le lọ si Tarṣiṣi.

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:37 ni o tọ