Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 20:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li ọjọ kẹrin nwọn kó ara wọn jọ li afonifoji Ibukún, nitori nibẹ ni nwọn fi ibukún fun Oluwa, nitorina ni a ṣe npe orukọ ibẹ na ni, Afonifoji Ibukún, titi di oni.

Ka pipe ipin 2. Kro 20

Wo 2. Kro 20:26 ni o tọ